Ọdẹrinde Oníjaàálá: Ìjálá mi máa ń mú káwọn onísẹ́ ibi gbàgbé láti sebi
Omisore Lateef Oyewale Ọdẹrinde sọ pe ti awọn ẹranko igbo ba ti gbọ ohun oun ni wọn yoo jade sita, ti oun yoo si fi ibọn pa iye to ba wu oun.
Ọdẹrinde ni bi ero ba se p si ni ori oun maa n wu, ere gbangba si ni oun maa n se.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
O fikun pe Ọ̀nà ni oun maa n rọ fun Ọọ̀ni ti Ilé Ifẹ̀, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọ̀jájá Kejì, lasiko to ba n jade bọ, ti gbogbo awọn eeyan to ba si ni lero lati se ibi yoo gbagbe ti oun ba ti n mi sẹ́ẹ́rẹ́ oun.
Bakan naa lo ni ti inu oun ko ba dun, ẹnikẹni to ba ya aworan oun sinu fidio ko ni ri lo rara, tori aworan naa yoo ti parẹ nigba to ba dele.