Seun Ayilara: Ó ni ohun tí Daddy Freeze ń wá lọ́wọ́ ìjọ RCCG

Àkọlé fídíò, 'Olórí ìjọ wa kò fẹ́ràn Daddy Freeze'

Láti ìgbà tí ọ̀rọ̀ gbájúgbajà sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ lórí Rẹ́díò, Daddy Freeze lórí ìdámẹ́wàá àti ọrẹ ti gbilẹ̀ kan káàkiri àgbáyé, àwọn olórí ìjọ ti ń ki àwọn ọmọ ìjọ wọn nílọ̀ káàkiri lórí ìhà tí wọn yóò kọ sí ọ̀rọ̀ náà.

Ọ̀gbẹ́ni Seun Ayilara fara hàn lórí fọ́nràn Daddy Freeze tán ni wàhálà bá bẹ́ sílẹ̀ nínú ìjọ rẹ̀. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé nígbà tí BBC Yorùbá kàn sí ìjọ náà, ìjọ ní àwọn kò lé ẹnikẹ́ni nínú ìjọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí