Omar Victor Diop: Ipa Áfíríkà nínú àkọsílẹ̀ ìwé kọja ògo tí wọ́n ń fún un lágbáyé

Àkọlé fídíò, Omar Victor Diop: Ipa Áfíríkà nínú àkọsílẹ̀ ìwé kọja ògo tí wọ́n ń fún un lágbáyé

Omar Victor Diop jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Dakar tí ó ń fi àwòrán yíyà sọ ìtàn ilẹ̀ Áfíríkà láti ọdún pípẹ́ sẹ́yìn. Omar ní inú dídùn sí Mímọ rírìi pé ibi kan ni gbogbo ìran adúláwọ̀ ti ṣẹ̀ wá.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: