D.O Fagunwa; Ǹkankan máa ń darí wọn lọ ibi tí a kò mọ̀
A bí i ní ìlú Oke Igbo, ìpínlẹ̀ Ondo ní ọdún 1903.
D.O Fagunwa ló kọ́kọ́ kọ ìwé kíkà Yorùbá àti ìwé l'édè Yorùbá. Fagunwa ló kọ́ Ògbójú Ọdẹ nínú Igbó Irúnmọlẹ̀, tí gbogbo àgbáyé mọ̀ ní ìwé kíkà àkọ́kọ́ ní èdè Yorùbá tó sì tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwé tí kọ́kọ́ kọ l'édè ìbílẹ̀ Áfíríkà.