NECO: Ẹ̀kọ́ Ìsírò, Gẹ̀ẹ́sì làwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti fọ́mọyọ

Awọn akẹkọ ileẹkọ girama to n sedanwo

Oríṣun àwòrán, AFP

Ajọ to n se kokari idanwo NECO ni orilẹede Naijiria, ti fi esi idanwo ti Neco June/July 2018 fun awọn akẹẹkọ ti girama.

Adele adari fun Ajọ NECO, Alhaji Abubakar Gana to kede eyi ni Minna, sọ wi pe awọn akẹẹkọ to fi orukọ silẹ fun idanwo naa to 1,041,536, ti awọn akẹẹkọ to to 1,032,729 si joko fun idanwo naa.

Ninu ọrọ rẹ, Gana ni ida aadọrun o le diẹ ni awọn akẹẹkọ to ni ‘Credit’ maarun ni Ẹkọ Isiro ati Ede Gẹẹsi ninu esi idanwo naa.

Awọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, Ileya: Àgbò wọ́n torí ọjà ẹran mẹ́ta ni wọ́n tìpa lókè ọya torí Boko Haram

Amọ, nigba to n ke gbajare wipe awọn akẹẹkọ ti ko joko se idanwo ni iwe idanwo, fikun wipe, awọn akẹẹkọ to to 20, 181 se magomago ninu idanwo naa, paapaa ninu Ẹkọ Isiro ati Ede Gẹẹsi.