Sodiq: Èmi kìí ṣe abokúsọ̀rọ̀ rárá, iṣẹ́ niṣẹ́ ń jẹ́

Àkọlé fídíò, 'Obìnrin tí kó ba fẹ́ òṣìṣẹ́ Mọ́ṣúárì, ìpinu rẹ̀ mẹ́hẹ'

Aliu Sodiq mú ìbẹ̀rù kúrò lọ́kàn àwọn ènìyàn nípà ìrírí mọ́ṣúàrì.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: