Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ àti ìyàwó rẹ̀ kò gbẹ́yìn nínú ìdìbò tó ń lọ

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Abiọla Ajimọbi àti ìyàwó rẹ̀ ló kọ́wọ̀ọ́rìn lọ sí ibi àpótí ìdìbò ti wọn.

Wọ́ọ̀dù kẹsàn-án nínú ọgbà ilé ìwé Girama ní Olúyọ̀lé, ìlú Ìbadan ní àpótí ìdìbò wọn wà gẹ́gẹ́ bí akọ̀ròyìn wa tó ń mójú tó ètò ìdìbò náà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sọ

wọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: