Davido: Mo fẹ́ràn Chioma púpọ̀, ọ̀la wa máa dára

Davido ṣe ìpinnu láti bá Chioma Avril gbé títí láí.

Gbajugbaja onkọrin nì, Davido Adeleke, ti fìfẹ́ hàn sí olólùfẹ́ rẹ̀, Chioma Avril, lasiko to n ṣe ayẹyẹ ọjọ ìbí ọdún metalelogun laye.

Davido fun un ni ọkọ̀ Porsche oní milionu marundinlaadọta naira pẹlu nọ́mbà Assurance niwaju ati leyin ọkọ̀ ọ̀hún fún ìsàmì ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Chioma.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

ÀJẸPỌ́NNULÁ