You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ní Àwòrán: Ètò Ìsìnkú Winnie Madikizela-Mandela
Ẹgbẹẹgbẹrun eniyan peju-pesẹ si ibi akanṣe eto iranti ati ayẹyẹ isnku fun gbajugbaja ọmọ orilẹede South Africa, Winnie Madikizela-Mandela. O figbakan jẹ iyawo aarẹ orilẹede South Africa tẹlẹri, Nelson Mandela ti o ku ni ọjọ keji oṣu kẹrin ọdun 2018.
Gbogbo awọn fọto/aworan wọnyi wà labẹ koko aṣẹ fun lilo wọn.