You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Fi owo osu rẹ we ajẹmọnu Sẹnatọ rẹ
Àwọn oṣiṣẹ Naijiria n beere fun ẹkunwo owo oṣu oṣiṣẹ to kere julọ pé kó jẹ ọgbọn ẹgbẹrun naira, bẹẹ ijọba ipinlẹ ati ti apapọ ni awọn ko lee san iye naa.
Laipẹ yi ni Sẹnetọ Shehu Sani sọ pe N13.5m ni owo ajẹmọnu osoosu awọn sẹnatọ.
Se owo yi kere tabi o pọju?
Elo gaan lo n gba losu?
Oya se idiwọn owo yi pẹlu owo osu rẹ?