Ẹṣọ oju-popo ti a ba ri ju 500 naira lọwọ re wọ gau

Àkọlé fídíò, FRSC o gbọdọ ni ju 500 naira lọwọ

Ọga awọn ẹṣo alaabo oju popo kan ti ke si awọn ọlọkọ ati awọn arinajo wi pe ki wọn pa ofin ọna mọ.

O tun sọ wi pe ẹsọ oju-popo ti o ba mu ju 500 naira lọwọ setan ati wọ wahala ijọba.

Ẹyin ero, e dẹkun ẹjọ rirọ ninu mọto pẹlu dirẹba awakọ ni imọran ti ajọ FRSC n ke tantan

Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si: