You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Eko: Ọja Alaba njona
Ọja Alaba to wa nipinlẹ Eko n jona lọwọ bayii.
Ẹnikan ti isẹlẹ ina naa soju rẹ sọ fun ileesẹ BBC Yoruba wipe ibudo ikerusi lo n jona ninu ọja naa.
Ọja naa to jẹ ọkan lara awọn ọja to tobi ju nipinlẹ Eko.