#NigeriaDecides2019: Awọn oloselu Naijiria ati awọn ẹbun ifẹ wọn

Aworan Mao Ohuabunwa
Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan tin ju oko ọrọ si Mao Ohuabunwa
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Oriṣii ọbẹ la n ri lọjọ ikú erin ni ọrọ ẹbun awọn oloṣelu lasiko idibo.

Laipẹ yi niroyin gbe wi pe Senator to n soju ẹkun idibo ariwa ipinlẹ Abia, MAO Ohuabunwa pin apẹ idinkara fun awọn eniyan lagbegbe to n soju nileegbimọ asofin agba Naijiria.

Ọgọrọ awọn ọmọ Naijiria ti bu ẹnu atẹ lu igbesẹ naa, bi o ti lẹ jẹ wipe Ohuabunwa ni "oun o kabamọ pinpin apẹ naa" ninu iroyin ti iwe iroyin fi sita.

Àkọlé fídíò, 2019: Wo fídíò bí wọ́n ṣe sọ nǹkan lu àwọn adarí APC l'Abẹokuta
Gomina Fayose

Oríṣun àwòrán, dfxmedia.wordpress.com

Àkọlé àwòrán, Gomina Fayose ti pin orisirisi ẹbun bi irẹsi ati adiyẹ adiyẹ
Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post

Kiiṣe Ohuabunwa ni oloselu ti yoo kọkọ pin awọn ẹbun ti a le tọka si bi eyi ti ko bojumu.

Wo awọn oloselu atẹbun arí ṣe haaa!

Omolanke

Oríṣun àwòrán, @SegunOladejo_

Àkọlé àwòrán, Orisirisi ẹbun to mu isọnu dani lawọn oloselu ti pin ni Naijiria

Gomina Ortum ti Benue naa ko gbẹyin ninu ẹbun rẹ

Shehu Sani pin rẹdio

Oríṣun àwòrán, ajayiwrites.blogspot.co.uk

Àkọlé àwòrán, Asofin Shehu Sani n soju ẹkun idibo aarin gbungbun Kaduna
Aworan agbada afẹfẹ gaasi
Àkọlé àwòrán, Mao Ohuabunwa n soju ẹkun ariwa ipinle Abia
Najeem Salam, Olori ileegbimọ asofin ipinlẹ Ọsun

Oríṣun àwòrán, gistmania.com

Àkọlé àwòrán, Olori ileegbimọ asofin ipinlẹ Ọsun naa pin tii alagbada
Àkọlé fídíò, Afẹnifẹre ni ọrọ atunto lawọ́n tori ẹ yan Atiku laayo