Ìfẹ́ ìlú àti Ìgbéleké orúkọ ẹ̀bì mi ló jẹ́ kí n díjé dupò gómìnà Oyo- Adelabu Adebayo

Adelabu Adebayo jẹ oludije labẹ ẹgbe\oṣelu Accord Party ni ipinlẹ Oyo.

Oludije ẹgbẹ oṣelu Accord Party nipinlẹ Oyo, Adelabu Adebayo sọrọ ilẹ kun lori awọn erongba rẹ fun igbayegbadun awọn eniyan ipinlẹ Oyo nibi ipade itagbangba ti BBC ṣe ni gbọngan Theophilus ni UCH ni ilu Ibadan.

O salaye nipa idagbasoke to fẹ mu ba eto ọgbin, eto ẹkọ ati eto aabo gbogbo awọn olugbe ipinlẹ Oyo ti ọkan wọn yoo si fi balẹ sii.

Gbọ awọn ilerio mii ti ọmọ Adelabu Penkelemes ṣe lati gbe oruko ididle rẹ ga sii ninu iselu Naijiria.