You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Adekunle Akindele tó jẹ́ alága PDP ti fèsi sí ẹ̀sùn tí APC fi kan pé PDP ń rán jàǹdùkú kọlu àwọn olóṣèlú APC ní Osun
Àwọn tọọgi ti APC kó jọ, ti wọn ra ibọn fun ti wọn ko ri owo 'settle' mọ lo n kọlu wọn nsiyi ni Osun kii ṣe awa PDP- Alaga PDP Osun.
Alaga PDP Osun, Adekunle Akindele ba BBC sọro lori ẹsun pé PDP n ran tọọgi lọ kọlu APC lẹyin iburawole gomina tuntun.
Alaga ẹgbẹ oṣelu PDP ti dahun si ẹsun pé PDP n ran janduku lati lọ kọlu awọn oloṣelu inu ẹgbẹ APC ni ipinlẹ Osun.
Alagba Akindele Adekunle to jẹ alaga ẹgbe\oṣelu PDP lo ba BBC yoruba sọrọ lori iṣẹlẹ naa.
O ni alaafia ipinle Osun lo jẹ PDP logun laisi wahala iselu ninu rara.
- Wo àṣírí bí àwọn 'influencer' ṣe ń gba owó lọ́wọ́ àwọn olóṣèlú láti tako ẹgbẹ́ òṣèlú míì
- Mínísítà, èèyàn mẹ́tàdínlógún mìí kú nínú bàálù tó já ní Ukraine
- Àwọn ọkùnrin tó ń bá ‘DJ’ jà nítorí orin lọ́jọ́ ìgbéyàwó fi òkúta fọ́ ìyàwó lójú
- -Mọ díẹ̀ lára nǹkan tí Alága ètò ìdìbò sọ ní Chatham House-
- Ilé ẹjọ́ dájọ́ ikú fún afurasí mẹ́rin ní Osogbo
- Ilé ìtura Premier Hotel da àwọn òṣìṣẹ́ sílẹ̀ bó ṣe kógbá wọlé báyìí