Wo àwọn asọ ìgbèyàwó àràmọ́ndà, kóo fojú lóúnjẹ òpin ọ̀sẹ̀

Igbeyawo je inawo ti o ni i se pelu okunrin ati obinrin ti won jo pinnu lati jo wa papo.

Bee ni ọ̀pọ̀ eeyan se gbagbo pe obinrin ni wọ́n maa n se pọ̀pọ̀sinsin julọ lasiko inawo igbeyawo