You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Libya Returnee: Odindi ọjọ́ kan ni mo fi wà ní ìhòhò ní Libya tí gbogbo èrò n fi ọwọ́ pa mí lára- Adenike Abode Libya
Adenike Olanipekun, ọkan lara awọn abọde Libya ti wọn n fi iriri wọn kọ ọpọ ọdọ Naijiria lẹkọọ sọrọ ilẹ kun.
O salaye gbogbo nkan ti oju rẹ ri lati igba to ti kuro ni Naijiria to fi de Ghana to tun fi de Libya.
Emi ati Iya mi ta gbogbo nkan ini wa ki n le ri owo mu lọ si Libya ṣugbọn ibanujẹ ni mo mu bọ lairi kọbọ kan fi ran ile lọwọ.
- Àlàyé lórí bí Báńkì àpapọ̀ Nàìjíríà ṣe tako ara rẹ̀, ó ní òun kò ní kí àwọn báńkì ó gba N500 àti N1000 àtijọ́ lọ́wọ́ aráàlú
- Fadeyi Oloro di aláìrílégbé, bú sẹ́kún bí pásítọ̀ Tobi Adegboyega ṣe ṣèrànwọ́ ₦3m fún un
- Mọ̀ síi nípa ewu tó rọ̀ mọ́ níní ìbálòpọ̀ lásìkò ìlóyún lórí ètò Sé lóòtọ́ ní BBC
- Ó kéré tán, ogún ọkùnrin ló n bá mi sùn lójúmọ́- Adenike Olanipekun
- Pásítòͅ kú lásìkò ààwèͅ ogójì oͅjóͅ tó gbà bíi ti Jesu
Adenike Olanipekun salaye pe awọn aadọta ni wọn n sun sinu iyara kan ṣoṣo.
Koda, o ni pe lati oju ọna ni awọn ọlọpaa ti n mu wọn ba sun lọkọọkan.
O ni Ibrahim aisha ni orukọ tuntun ti wọn fun oun nibẹ.
O sọ nipa ifipabanilopọ ti oju rẹ ri.
- Mọ̀ síi nípa ewu tó rọ̀ mọ́ níní ìbálòpọ̀ lásìkò ìlóyún lórí ètò Sé lóòtọ́ ní BBC
- Ta ló gbé igbá fún Mama Rainbow láti ṣí wò-
- Ìdìbò tó ń bọ̀ yìí, Ọrọ̀ ta ló tọ́, ta ni Ifa mú ni, Asiwaju Tinubu sì ni Ọlọ́run rán! – Oba Elegushi
- Aláàfin Adeyemi ló mú mi fẹ́ràn àṣà Yorùbá síi pẹ̀lú iṣẹ́ ìwádìí- Paula Gomez, Oyìnbó tó ń gbé àṣà Yoruba ga
- Wọn kò tíi bí ọkùnrin tí kìí ṣe ṣìná sáyé- Olori Sekinat Elegushi
Adenikẹ gba awọn ọdọ Naijiria ni imọran, o tun ranṣẹ si ijọba Naijiria lori ọrọ irinajo tipatipa lo silẹ okeere to wọpọ laisko yii.
O ni ẹgbẹrun marun un naira ni ijóba pin fun wọn lati fi lọ bẹrẹ iṣẹ lẹyin to de pada sile.