Tokyo 2020 Olympics: Àwọn eléré ìdárayá ilẹ̀ Afrika tó yẹ kí o wò

Odun 2020 lo yẹ ki idije ere idaraya Olimpiki Tokyo 2020 ko waye, sugbọn wọn sun siwaju nitori aarun coronavirus si 2021.

Gẹgẹ bi awọn ere idaraya Olimpiki Tokyo yii yoo ṣe bẹrẹ ni ọjọ kẹtalelogun (23) oṣu keje, 2021, a n fi asiko yii wo awọn elere idaraya ilẹ Afrika to yẹ ko wo ninu idije yii.

Awọn elere idaraya wọnyi ni a yan lati orisirisi ere idaraya leyi ti wọn kò ṣe awọn miran ni apa ilẹ Afrika ati wipe ara awọn olukopa yii leti ni iriri olimpiki tẹlẹ ri tabi kò jẹ fun igba akọkọ wọn.ii.

Ilana ta lo:

Awọn elere idaraya Afirika wọnyi ṣe aṣoju awọn oriṣiriṣi awọn agbegbe nílẹ Afrika. Wọn yan wọn lori iriri wọn ní Olimpiki, awọn ami ẹyẹ ti wọn gba ati iyasọtọ ti iṣẹlẹ ere idaraya wọn.

Igboriyin:

Olootu atẹjade Nkechi Ogbonna, Princess Abumere pẹlu Muthoni Muchiri. Ayaworan Olaniyi Adebimpe àti Millicent Wachira. Iṣẹ ayelujara: Purity Birir. Atilẹyin afikun: Sally Morales and Celestine Karoney.

Aworan:

Getty Images, The International Basketball Federation, AFP, Nigerian News, Nigerian Rowing Canoeing and Sailing Federation, Nigerianews, Mekseb Debesay, Sailing Club of Mozambique, Giana Farouk, EPA, Press Focus/News Pix via PA, Erwythereyet via Twitter, Bruce Viaene via Olympics, ClimbZA, DW via Club of Mozambique.