Yoruba Movie Actors On Set vs Off Stage: Bí àwọn òṣèré fíìmù ṣe rí láì mura gegege

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Pẹlu bi awọn oṣere ṣe rẹwa to ti awọn eeyan si maa n wari fun wọn lori itage paapaa nigba ti wọn ba ti kun oju kun ara fun wọn tan ti aṣaraloge si ti ṣe iṣẹ tirẹ, ati wa maa tun sọ airẹwa wọn maa n jẹ iyalẹnu.

Ni ọpọ igba, arumajẹ ati itanjẹ ni ọpọ gbajumọ oṣere n fi ẹwa ti wọn n gbe saye ṣe lori ayelujara wọn ati ninu awọn ere wọn.

Ọpọ nkan imọ ẹrọ lo ti wa bayii to si jẹ pe ko gba wọn ni iṣẹju pupọ lati lo o mọ ara wọn bi wọn ba fẹ ya fọto.

Fun apẹrẹ, wọn a maa lo Aapu kan to n jẹ "Fliters" lati fi yọ ohun bii kurukuru to ba wa loju wọn ṣaaju ki onifọto to ya wọn.

Bakan naa awọn ipara, nkan ikunra, atike ati ikunte ti wọn maa n lo gan n ṣe iṣẹ agbara.

Lara bi oju wọn ṣe ri eyi taa ka mọ ree nigba ti wọn o kun ọda ologe soju tabi ara wọn ati lai lo Filters

Fausat Balogun (Madam Saje)

Aisha Lawal

Ibrahim Chattah

Queen Salawa Abeni

Mide Martins

Mustapha Sholagbade

Idowu Phillips (Mama Rainbow)

Lawal Rukayat (Iyabadan)

Toyin Abraham

Jaiye Kuti