Journey to Europe: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìnira lojú àwọn ọ̀dọ́ ilẹ̀ Áfíríkà tó ń wá ìgbé ayé rere lọ sí Yúróòpù ń rí
Lọna ati ri ojuna rere fun ọjọ ọẹa wọn, ọpọ ọdọ lo ti morile ilẹ Yuroopu fun papa oko tutu.
Amọṣa oniruuru ipenija ni wọn n koju ti ọpọ ẹmi si ti ṣofo pẹlu.
Oniruuru iriri lawọn ọdọ wọnyii n ri koda ọpọ ninu wọn lo ti ba awọn oniroyin sọrọ lori awọn ohun ti wọn n ba pade nibẹ.
- Obìnrin tó ń ṣiṣẹ́ ẹrú ní Oman tó bá fẹ́ òmìnira, yóò bá ọ̀gá rẹ̀ ṣùn - obìnrin méjì tó ti oko ẹrú dé
- Ìtàn ayé Taiwo Oredein rèé, àgbà òṣèlú tó parí ayé rẹ̀ sọ́gbà ẹ̀wọ̀n
- Ó dá mi lójú pé ọmọ ìjọ mi kò lé è kó àrùn Coronavirus - Adeboye
- Èdè àìyedè bẹ̀rẹ̀ lórí bí àgbélẹ̀rọ òyìnbó Nàíjíríà ṣe wọ ìwé atúmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì Oxford
- Ògbólógbòó ìjàpá rèé, tó bí ọmọ 800 kí ìran rẹ̀ má ba à parun
- Wo àwọn ọmọbìnrin tó mu ìtọ̀ ara wọn nítorí òùngbẹ aṣálẹ̀ Sahara