You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ministerial List: Buhari tí dájọ tí yóò búra wọle fún àwọn mínísítà rẹ̀
Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò búra fún àwọn mínísítà rẹ̀ ní ọjọ kọkànlélógún oṣù kẹjọ ọdún 2019.
Ààrẹ sọ èyí di mímọ̀ lóri ẹ̀rọ twitter rẹ̀.
Gẹ́gẹ́ bí àkọwé ìjọba àpapọ̀ ṣe sọ Boss Mustapha sàlàyé pé ayẹyẹ ìbúrawole náà yóò wáye níu ilé ìjọba lásìkò ìpàdé ìgbìmọ aláṣẹ́