Nigeria vs Madagascar: Super Eagles ń gbáradì fún ọjọ́ àìkù
Awọn ọmọ ikọ agbabọọlu Naijiria ti n gbaradi kikan kikan lati gbena woju ikọ agbabọọlu Madagascar.
BBC Yorùbá ní gbólóhùn pẹ̀lú àwọn agbábọ́ọ̀lù Super Eagles ní Egypt
O ranti bi wọn ṣe ṣe e pẹlu ikọ Burundi ti wọn fi da sẹria fun wọn pe ik Burundi ba awọn wọ ọ gan ni ṣùgbọ́n Naijiria pada borí.
John ni awọn ko ni kẹrẹ rara ninu igbaradi fun ifẹsẹwọnsẹ eyi ti yoo waye lọjọ aiku pẹlu Madagascar.