You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
BBC ṣe ìwadìí lórí bí ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ṣe ń mú kí àwọn ọkùnrin lórílẹ̀èdè Kenya ó máa gb'ẹ̀mí ara wọn
Ni ẹnu lọwọlọwọ yii, iwadii ti fi idi rẹ mulẹ pe iṣẹlẹ dida ẹmi ara ẹni legbodo ti wọpọ bayii laarin awọn ọkunrin lorilẹede Kenya. Iwadii naa si tun fi idi rẹ mulẹ pe iporuru ọkan, (Depression lo n ṣokunfa eyii.