BBC ṣe ìwadìí lórí bí ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ṣe ń mú kí àwọn ọkùnrin lórílẹ̀èdè Kenya ó máa gb'ẹ̀mí ara wọn

Àkọlé fídíò, BBC ṣe ìwadìí lórí bí ìpòrurù ọkàn ṣe ń pa àwọn ọkùnrin lórílẹ̀èdè Kenya

Ni ẹnu lọwọlọwọ yii, iwadii ti fi idi rẹ mulẹ pe iṣẹlẹ dida ẹmi ara ẹni legbodo ti wọpọ bayii laarin awọn ọkunrin lorilẹede Kenya. Iwadii naa si tun fi idi rẹ mulẹ pe iporuru ọkan, (Depression lo n ṣokunfa eyii.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: