Sibahle Zwanen fi ìmọ̀ ìṣìro da orí ayélujára rú
Ọmọ yii ma n wa idahun si awọn iṣiro to le lai lo kakuletọ.
Sibahle Zwanen to jẹ ọmọ orilẹede South Africa mọ iṣiro, debi wi pe o n fa ariyanjiyan lori ẹrọ ayelujara.
Okiki rẹ kan nigba ti ọlọpaa kan ni agbegbe rẹ ya fidio rẹ nibi to ti n wa idahun si awọn ibeere iṣiro to le.
Akọroyin BBC, Pumza Fihlani, dan an imọ ọmọ naa wo

