#SaveRahat: Ẹ wo agbára lílo ẹ̀rọ ayélujára lọ́nà tó tọ́.
Rahat Mohammed jẹ ọmọ ọdun mejidinlogun tó sa kuro nile fun awọn ẹbi rẹ.
Ó kígbe síta lójú opo ikansiraẹni Twitter pe ki gbogbo agbaye gba oun o tori awọn obi rẹ.
Kò pẹ́ rara si akoko to bẹrẹ si ni s ohun ti o n la kọja loju opo Twitter ti awn eniyan si ti n dide iranwọ.
Oju opo Twitter jẹ ibi ti eniyan ti le sọrọ ko si gba esi rẹ lọgan nitori gbogbo eniyan lo le ri ohun ti ẹlomiiran ba kọ niwọn igba ti wọn ba ti dọrẹẹ.
Koda bi ẹnikan ko ba ki n ṣe ọrẹ Rahat fun apẹẹrẹ, ọrẹ ẹni naa to jẹ ọrẹ Rahat lee jẹ ko ri i bi o ba pin in tabi sọrọ lori ẹ́.