Afrika Shrine: Àsà Yorùbà gbayì lójú Ààrẹ ilẹ̀ Faranse

Àkọlé fídíò, Ijó Yorùbá ni wọ́n fi kí Ààrẹ Macron káàbọ̀

Gbogbo àwọn tó wà níbí ètò fún àjọsepọ̀ àgbéga àṣà láàrin orilẹ̀èdè Nàìjíríà àti ilẹ̀ Faranse dára yá pẹ̀lú ijó ìbílẹ̀ Yorùbá.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí

Àkọlé fídíò, Ààrẹ Buhari ti gba Ààrẹ Macron ti orílẹ̀èdè France lálejò nilu Abuja