Ènìyàn méjìdínlọ́gbọ̀n lo ṣe pẹ̀kí ọlọ́jọ́ wọn ni Mubi

Àwọn osise isele pajawiri
Àkọlé àwòrán, Ènìyàn tó lé laadodota lo fara káasa nínú ìṣẹ̀lẹ̀ náà.

Ènìyàn méjìdínlọ́gbọ̀n lo tí ṣe pèkí ólọ́jọ́ wọn lónìí níbi Ìkọlù to ṣẹlẹ̀ nínú mọṣalaṣi kan lápá ariwa- ìlà-ọrùn ìpínlẹ̀ Adamawa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àjọ tó ń rí si ìṣẹ̀lẹ̀ pajawiri (NEMA) lo fìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀, ó fi kún un pé ènìyàn tó lé láàdọ́ta lo fara káasa nínú ìṣẹ̀lẹ̀ náà.Àwọn agbésùmọ̀mí méjì ló ṣíṣe ńlá ibi òhún nínú mọsalasi kan, nígbà tí ikejì wáyé ní ìgboro Mubi tó jẹ́ ààlà orile-ede Naijiria àti Cameroon.