Àjàgbé Toriola Oyewo: Ọdún 1999 ni mo tí ń gbìyànjú láti gba SAN kí wọ́n tó fún mí ẹ̀ní ọdún 90

Amofin Agba, Ajagbe Toriola Oyewo ni itan aye rẹ ṣe apejuwe bi eniyan ko ṣe gbọdọ ro ara rẹ pin ti nkan ko ba lọ bi o ṣe yẹ ko lọ.

Ajagbe Toriola di agba Amofin SAN ni ẹni aadọrun ọdun lẹyin gbogbo igbiyanju rẹ lati bi ogun ọdun mejilelogun ṣẹyin.

Baba Oyewo ni ọdun 1999 ni ohun ti n tiraka lati gba SAN, ọkan lara awọn to gba oye SAN mọ lọwọ ni Gani Fawehinmi ni ọdun 2001.

Ẹkunrere fidio naa sọ iriri rẹ laye ati bi o ṣe laaja.