EndSars Protest;Oluwapọ̀nmile sọ ìrírí rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn sójà tó fìyàjẹ́ ní Ibadan

Àkọlé fídíò, EndSars Protest;Oluwapọ̀nmile sọ ìrírí rẹ̀ lọ́wọ́ à

Arakunrin Ẹmiọla David Oluwapọnmile ṣe alabapade ikọ ologun "Operation Burst" ni agbegbe Bẹẹrẹ nilu Ibadan ti wọn si fi abẹ ṣekele fa irun ori rẹ.

Iredi ti ikọ naa fi ṣe bẹẹ ni ko si han si ẹnikẹni titi di asiko yii.

Oniṣowo ni Ẹmiọla, bakan naa lo si jẹ agbẹ ọlọsin adiyẹ.