EidAlFitr2019: Bó ṣe ń lọ káàkiri àwọn Yidi rèé

Ẹ kú ọdún ìtúnu àaàwẹ̀ gbogbo ẹ̀yin olólùfẹ́ BBC Yoruba, a muú àwọn àwòrán bi àdúà ṣe ń lọ ni àwọn Yidi ni agbègbè wa.

Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyó
Àkọlé àwòrán, Gomina Oyo nigba kan ri, Rasheed Ladoja naa de Yidi
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyó
Àkọlé àwòrán, Adua a gba o
Sultan ti Kano ati Gomina Ipinlẹ Kano pade ni Yidi
Àkọlé àwòrán, Sultan ti Kano ati Gomina Ipinlẹ Kano pade ni Yidi
Aarẹ Muhammadu Buhari naa lọ Yidi
Àkọlé àwòrán, 'Baba, ẹ ba wa lọwọ adua'
Aarẹ Muhammadu Buhari n gbadura ni Yidi
Àkọlé àwòrán, Aarẹ Muhammadu Buhari ati ọmọ rẹ ọkunrin
Aarẹ Muhammadu Buhari lọ Yidi
Àkọlé àwòrán, Ti ẹṣiṣi ba fo gan nibi ti Aarẹ wa gan, awọn alaṣọ dudu wọnyii yoo han!
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni pinlẹ Eko
Àkọlé àwòrán, Ẹ ń lẹ́ ń bẹun o!
Ọmọde ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni pinlẹ Eko
Àkọlé àwòrán, Bíntín logé ti ń bẹ̀rẹ̀
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyó
Àkọlé àwòrán, Ẹ gbé ìrun dúró
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyó
Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọ ọlọdun ree to gan pa fun fọto
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyó
Àkọlé àwòrán, Awọn oniṣowo ko gbẹyin
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyọ
Àkọlé àwòrán, Toju ko ba ri daradara, ẹ fi igo kaa.
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyọ
Àkọlé àwòrán, Ọmọ Ibadan, ki ni so?
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyọ
Àkọlé àwòrán, Awọn musulumi ododo nipinlẹ Ọyọ naa darapọ mọ awọn akẹgbẹ wọn lagbaye lati ṣe ajọyọ ọdun itunu awẹ.
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyọ
Àkọlé àwòrán, Ibadan, Ipinlẹ Oyo
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyọ
Àkọlé àwòrán, Ko si alaabọ ara niwaju Eleduwa
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyọ
Àkọlé àwòrán, Yidi Ibadan ni Ipinlẹ Oyo