Àwòrán mánigbàgbé BBC news Yorùbá fún ọ̀sẹ̀ yìí

Èyí ni àkójọpọ̀ àwọn oun tí ojú wa rí ní ìgboro ní ọ̀sẹ̀ yí

Arákunrin kan wọ aṣọ òyìnbó ni Ibadan
Àkọlé àwòrán, Iṣẹ́ loógùn ìṣẹ́
Arakunrin kan n ta oṣan ni Ibadan
Àkọlé àwòrán, B'ọ̀sàn bá dùn, máà mu igba
Arakunrin meji kan ni gbe ẹran lọwọ
Àkọlé àwòrán, Ẹran ọbẹ̀ ní gbangba òde...
Àwọn ará Ipinlẹ Osun ko ilu síta láti ṣe ajọyọ idajọ ile ẹjọ kotẹmilọrun tó gbade fun Gboyega Oyetola ti APC
Àkọlé àwòrán, Àwọn ará Ipinlẹ Osun ko ilu síta láti ṣe ajọyọ idajọ ile ẹjọ kotẹmilọrun tó gbade fun Gboyega Oyetola ti APC
Arabinrin kan fẹ ra ounjẹ didin ni Ibadan
Àkọlé àwòrán, Dùndún, àkàrà tàbí ẹran díndín, ẹ mú tiyín níbẹ̀