You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Buruji Kashamu: Èmi ṣì ni olùdíje PDP ní Ìpínlẹ̀ Ogun
Agbẹnusọ fún Sẹ́nétọ̀ Buruji Kashamu, Austin Oniyokor, ni ọ̀gá òun ṣì ni olùdíje fún ipò gómínà lábẹ́ àṣíá ẹgbẹ́ òsèlú PDP ní Ìpínlẹ̀ Ogun.
Ó ni ọ̀tọ̀ ni ẹjọ́ tí ilé ẹjọ́ kòtẹ́nmilọ́rùn sọ, ọ̀tọ̀ ni ìròyìn ń gbé jáde.