Tony Elumelu 2018: Mahassin Quadri ló gbà ìrànwọ owó

Ọdọọdun ní Tony Elumelu Foundation máa ń fún àwọn ọdọ tí wọn ni ìmọ̀ lóri ètò ọrọ̀ ajé láti wa sọ tẹnu wọn lọ́rí owò túntun.

Mahassin Quadir pkún fun ìyanu ojiji tó de bá
Àkọlé àwòrán, Lẹyin ti wọn fún olukopa kọọkan láàyè láti sọ nípa ohun ti wọn o fi owó wọn ṣe ti wọn ba gbàá
Awọn agbátẹrùn
Àkọlé àwòrán, Mahassin Quadri lo gbá ẹbùn owó $5000 níbí ètò ìdíjè Tony Elumelu tọdún 2018
Jessica Rakotorisoa
Àkọlé àwòrán, Kìí ṣe Mahassin nikan ló kopa nínú ìdíje náà, ọ̀pọ̀ àwọn ọdọ̀ míràn náá wá láti oníruuru orilẹ̀-èdè. Lara wọn ni yìí lasìkò tó sọ bí yóò ṣe ná owo náà
Mahassin ń sọ̀rọ̀
Àkọlé àwòrán, Mahassin ṣe àgbékalẹ̀ ohun elo ìmọ ẹ̀rọ fún àwọn ìyálajé àti àwọn onísòwò láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọ̀rọ̀ àjé wọn tí o ń pè ní MadamCash. Iwulo aapù ọhun ní láti fun àwọn ìyálọ́jà l'áànfàni láti mọ bi ọjà wọn ṣe ń lọ́ sí.
Awọn onísowo tó wá tẹ́t si ọgbọn ìsòwò ti àwọn ọ̀dọ́ náà ń gbe kalẹ̀
Àkọlé àwòrán, Awọn èèkàn tó wá yẹ èto ọlọdọọdún tí Tony Elumelu máa ń ṣe yìí sí ni Ààrẹ orílẹ̀èdè Ghana
Wọn gbé àmì ẹyẹ fún
Àkọlé àwòrán, Mahassin yìí ó ti kọ̀kọ́ gba ẹgbẹ̀rún mẹ́fà dọ́là fún áápù Cashmadam tó ṣe,sùgbọn ní báyìí yóò tún gbà ẹgbẹ̀rún lọ́nà ààdọ́ta dọ́là láti fi mú ìdàgbàsókè bá áápù nàá
Gbọgba ìpàdé ètò ọhun
Àkọlé àwòrán, Ọdọọdun ní Tony Elumelu Foundation máa ń fún àwọn ọdọ tí wọn ni ìmọ̀ lóri ètò ọrọ̀ ajé ní ànfàání láti wa sọ tẹnu wọn lọ́rí ọ̀nà úntun ti etò ọ̀rọ̀ ajé le gba ní Afirika