You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ìdíje ata tútù: Sé o le è kópa nínú ìdíje jíjẹ ata tútù?
Idije ata tutu ni agbegbe Human ni orilẹ́ ede China kii se ere rara.
Laarin isẹju kan ni ẹni to bori idije naa jẹ ata aadọta, to si gba ẹbun owo goolu to jẹ giramu mẹta.
Oludije mejila lo kopa ninu idije naa.