Aworan abẹwo Aarẹ Buhari si ipinlẹ Plateau

Aarẹ Muhammadu Buhari n ṣe abẹwo ọlọjọ meji si ipinlẹ Plateau.

Awọn eniyan tu jade si oju popo lati kii Aarẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Ogunlọgọ awọn eniyan tu jade si oju popo lati kii Aarẹ Buhari kaabọ si ipinlẹ Plateau lọjọ ọjọbọ.
Awọn eniyan tu jade si oju popo lati kii Aarẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Awọn alakoso aabo fun aarẹ Buhari ni idokukọ awọn eeyan ti wọn rọ jade soju ọna.
Ọdọmọkunrin kan duro si oju ọna niwaju ọkọ ayọkẹlẹ Aarẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Ọdọmọkunrin kan duro si oju ọna niwaju ọkọ ayọkẹlẹ Aarẹ Buhari
Ọdọmọkunrin kan duro si oju ọna niwaju ọkọ ayọkẹlẹ Aarẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Ọdọmọkunrin kan duro si oju ọna niwaju ọkọ ayọkẹlẹ Aarẹ Buhari nipinlẹ Plateau
Aarẹ Buhari ṣe ipade pẹlu awọn alẹnulọrọ nipinlẹ Plateau

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Aarẹ Buhari ṣe ipade pẹlu awọn alẹnulọrọ nipinlẹ Plateau
Ipade Aare Buhari pelu awon loba-loba nilu Jos

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Ipade Aare Buhari pelu awon loba-loba nilu Jos
Awọn eniyan ipinlẹ Plateau tu jade si oju popo fun igbalejo Aarẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad

Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan ipinlẹ Plateau tu jade si oju popo fun igbalejo Aarẹ Buhari