You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kemi Korede: Ni iléeṣẹ́ búrẹ́dì tí mo ti n ṣiṣẹ́ ni ọmọ mi kẹta ti sọnù títí di òní yìí, mo ṣì nírètí pé màá rí Anthony mi
Mo lọ ya owó gúmí láti fi wa ọmọ mi kẹta tó sọnù- Kemi Korede.
Lásìkò tí Taiwo n nu omijé Kemi aya rẹ̀ ló pàrọwà fún gbogbo ẹni tó n la ìṣòro ọmọ kọja pé kí wọ́n má sọrètí nú nítorí pé aláànú ni Olodumare yóò mu inu kóówà dùn nígbẹ̀yìn!
Taiwo Korede ati Kemi Iyawo rẹ ti won n gbe ni agbegbe Rander ni Abeokuta ni ipinle Ogun lo sọ die ninu ohun ti ojú wọn ti ri lori ọro ọmọ.
Wọn sọ bi wọn ṣe padanu omo meji ti iketa si sọnu pelu ibanujẹ ọkan ki Olorun to tun fi awọn ọmó miran kẹ wọn.
Taiwo ati Kemi gba awọn to n la iṣoro ọmọ kọja lati ma ro ara wọn pin nitori pe alaanu ni Oba Oke to n ṣe eyi to wu u lori ẹda.
- Wo oríṣì mágùn mẹ́sàn-án tí wọ́n n lé sí ara obìnrin nílẹ̀ Yorùbá
- Ikú ẹ̀gbọ́n mi kò gbọdọ̀ lọ lófo– àbúrò tọkọtaya tí wọ́n dána sun ní Abeokuta pàrọwà síjọba
- Pósí oríṣí mẹ́ta ni Pope Benedict yóò sùn sí kí òkú rẹ̀ tó wọ ilẹ̀
- Alákoso ìpàdé orin 'Concert' fojú ba ilé ẹjọ́ nítorí pé ẹni mẹwàá kú
- Ará ìlú yarí lórí àìsì owó náìrà tuntun gbà ní bánkì
- Ó kéré tán ìkọ̀ ọmọogun Russia 400 ló kú ní ìkọ̀lù àdó olóró – Ukraine