Festac Explosion: Àwọn àwòràn tó ṣeni ní àánú níbi ìbúgbàmù Eko

Ibugbamu to waye ni adugbo Festac nilu Eko lọjọ Aiku ba ọpọlọpọ dukia jẹ, to si mu ẹmi eeyan lọ,

Ọkọ yii jona, o tun run kọja aala nibi ibugbamu agbegbe Festac

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Ọkọ yii jona, o tun run kọja aala nibi ibugbamu agbegbe Festac
Bi awọn dukia kan ṣe wo kanlẹ, ni wọn tun jona

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Bi awọn dukia kan ṣe wo kanlẹ, ni wọn tun jona
Awọn ara adugbo naa tu jade, ti wọn si n duro ni mẹta-mẹẹrin lati jiroro lori iṣẹlẹ aburu naa

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Awọn ara adugbo naa tu jade, ti wọn si n duro ni mẹta-mẹẹrin lati jiroro lori iṣẹlẹ aburu naa
Ọkọ ayọkẹlẹ miran tun re e, ohun naa fara gba lara ibugbamu naa

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Ọkọ ayọkẹlẹ miran tun re e, ohun naa fara gba lara ibugbamu naa
Ọkọ ayọkẹlẹ jiipu to bajẹ nibi iṣẹlẹ naa

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Iṣẹlẹ naa ko yọ awọn ọkọ ti wọn paaki silẹ, ibugbamu naa lo fọ gbogbo gilaasi ọkọ yii
Ọpọlọpọ ile alarambara lo wo, jona lasiko ibugbamu naa

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Ọpọlọpọ ile alarambara lo wo, jona lasiko ibugbamu naa
Ile alaja kan re e to wo lati oke de ipilẹ nibi ti agbara ibugbamu naa to

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Ile alaja kan re e to wo lati oke de ipilẹ nibi ti agbara ibugbamu naa to
Ọkan tun re e lara awọn ọkọ ayọkẹlẹ ti ibugbamu fi ọwọ ba, a ko le sọ boya ina tabi ile to wo lo sọ ọkọ yii di rirun jege-jege

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Ọkan tun re e lara awọn ọkọ ayọkẹlẹ ti ibugbamu fi ọwọ ba, a ko le sọ boya ina tabi ile to wo lo sọ ọkọ yii di rirun jege-jege
Ọkan lara awọn ile to wa ninu ọgba ileewe Bethlehem ti ibugbamu naa fọwọ ba niyii.

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Ọkan lara awọn ile to wa ninu ọgba ileewe Bethlehem ti ibugbamu naa fọwọ ba niyii, awọn akẹkọọ to n gbe ninu ọgba ileewe naa farapa
Ọpọlọpọ ile lo wo kanlẹ patapata lẹyin iṣẹlẹ ibugbamu naa

Oríṣun àwòrán, others

Àkọlé àwòrán, Ọpọlọpọ ile lo wo kanlẹ patapata lẹyin iṣẹlẹ ibugbamu naa