Àrà rèé: Wo ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tó ń fò lójú òfurufú

Àkọlé fídíò, Àrà rèé: Wo ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tó ń fò lójú òfurufú
Àrà rèé: Wo ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tó ń fò lójú òfurufú

Bi aye n yi ni ka ma ba yi, lo di fun Ileeṣẹ tuntun kan ni US, ti fi fidio kan sita lati ṣafihan ọkọ ayọkẹlẹ to n fo.

Bẹẹni ọkọ ayọkẹlẹ to n fo, koda, o dabi ọkọ yooku, o si n ṣiṣẹ bi i wọn.

O le wa ọkọ naa nilẹ, gbera kuro nilẹ, ki o si fo, lai yi ọwọ iṣẹ pada

Lasiko sunkẹrẹ-fakẹrẹ tabi idiwọ kan. O le fo lori odo tabi ohunkohun, ki o si maa wa ọkọ rẹ lọ.

Ọkọ yin le fo lati ibẹrẹ irinajo rẹ titi de opin nipa lilo ijanu 'bi-plan mode'.

Alef Aeronautics, ikawọ rẹ ni gbogbo eyi wa, gẹgẹ bi awakọ

O ṣoro lati mọ ninu fidio yii, boya ẹnikẹni wa ọkọ naa.

Amọ ileeṣẹ naa sọ pe awakọ baalu kan wa ninu rẹ lasiko ti wọn ya awọn aworan naa.

Aabo to daju wa fun awọn to ba n lo ọkọ naa.

O nilo lati ni oye nipa awọn ilana oju ofurufu.

Aworan Oko ofurufu

Oríṣun àwòrán, Alef Aeronautics