Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Gbogbo ọmọ Naijiria lo gbọdọ ṣiṣẹ papọ ti Naijiria yoo ba de ebute ogo

Aarẹ Naijiria, Bola Tinubu sọ èyí nigba to n ba awọn aṣofin sọrọ ni ayajọ ominira

Tinubu ni oriṣiriṣi orukọ to wu awọn eeyan ni wọn n pe oun nitori oṣelu

Ṣe ko sọrọ lori iṣẹ ati oṣi ni?

Kan soju opo bbc news.com/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Ẹ fopin si iṣẹ ati oṣi

Eto iṣejọba to duro ire la n fẹ

Ominira ni June 12 wa fun

Eyi lawọn akọle tawọn olufẹhonuhan to n ṣewọde kaakiri Naijiria gbe dani

Lati ṣami ayajọ ọjọ ominira to n waye lonii

Ipinlẹ Osun, Ondo, Eko, Oyo, Abuja ni iwọde naa ti waye

Tawọn oluwọde si n beere fun igbe aye irọrun ni Naijiria

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Eeyan to le ni igba ti padanu ẹmi wọn

Bi ọkọ ofurufu to gbera lati Ahmedabad, India lọ si London ṣe ja lulẹ lẹyin iṣẹju kan to gbera

To si ja le ibugbe awọn dokita lagbegbe Meghani Nagar

Awọn alaṣẹ ni iṣẹ idoola n lọ lọwọ

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́