Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Asasi lo mu mi pa ọmọ mi loṣu kan abọ
Asasi kẹ!
Orin ko ye emi naa lo gbẹnu Micheal Ifagbenga to fi ọbẹ dunbu ọmọ rẹ lọsẹ to kọja
Ah, iyẹn ma tun lagbara kẹ
Ifagbenga ni ẹmi kan lo ṣadede wọ inu oun nibi toun ti n kọṣẹ babalawo nipinlẹ Ogun lati lọ pa ọmọ naa nibi ti iya rẹ tẹ si ninu yara
Ki lo wa ṣẹlẹ si bayii?
Kan si oju opo bbc.com/yoruba fun ẹkunrẹrẹ
Awọn aarẹ orilẹ-ede ni oorun Afrika ti fẹnuko lati ṣe ọna kan ti yoo so orilẹ ede marun-un pọ
Ọna ọhun ti ireti wa pe yoo so Ivory Coast, Ghana, Togo, Benin Republic ati Nigeria papọ ni wọn yoo ṣe fun ọdun mẹjọ bẹrẹ latọdun 2026
Ireti wa pe yoo pese iṣẹ fun eeyan to le ni ẹgbẹrun lọna aadọrin
Ta ni yoo dade agbabọọlu to pegede julọ nilẹ Afirika fọdun 2024?
Lalẹ oni ni idahun ibeere yii yoo waye nibi ayẹyẹ CAF awards ni Morocco
Awọn wo lo n dije fun ami ẹyẹ naa gan lọdun yii?
Fun ẹkunrẹrẹ
