Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Ẹgbẹ awọn akẹkọọ nipinlẹ Ondo ti ṣe iwọde tako kọmiṣọna fun eto idajọ ipinlẹ naa, Kayode Ajulọ

Lẹyin ti wọn fẹsun kan pe o lo agbara rẹ lati fi awọn akẹkọọ kan si atimọle ọgba ẹwọn ilu Akure

Awọn akẹkọọ ọhun ni ede aiyede kan lo waye larin awọn ati adajọ agba naa, ko to lo ọwọ agbara fun wọn

Ẹkunrẹrẹ wa loju opo BBC Yoruba

_____________________

Obinrin kan ti wọn bi lai ni ile ọmọ ti pada bimọ nilẹ Gẹẹsi

Ara meeriri!

Ẹni ọdun mẹrindinlogoji ni Grace Davidson wa lai lọmọ laye ki ibatan rẹ kan to fun nile ọmọ tirẹ

Amy ni wọn so ọmọ tuntun naa lati bu ọla fun ibatan to fun iya rẹ nile ọmọ

____________________

Nipinlẹ Ogun

Ijọba ibilẹ Ifo ti sọrọ soke lẹyin ti BBC Yoruba tun aṣiri awọn kọlọrọsi to n fi ipa gba owo lọwọ awọn awakọ lagbagbe Ojodu-Abiodun

Alaga ijọba ibilẹ Ifo, Idris Olalekan Kushimo ni kii ṣe ijọba ibilẹ naa lo rab awọn kọlọrọsi naa niṣẹ

Fun ẹkunrẹrẹ bi a ṣe fi oju awọn afipa gbowo naa lede