You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Fídíò nípa ìtàn ayé Ọbabìnrin Elizabeth kejì tó jáde láyé
Fídíò nípa ìtàn ayé Ọbabìnrin Elizabeth kejì tó jáde láyé
Ọbabinrin Elizabeth Keji ti ilẹ Gẹẹsi ni ori ade to pẹ julọ lori oye nilẹ naa.
Ọjọbọ, ọjọ kẹjọ, oṣu Kẹsan an, ọdun 2022 yii ni Ọbabinrin Elizabeth waja.
Ẹni aadọrin ọdun ni ki ọlọjọ to de.
Westminster Abbey ni wọn ti dade fun Elizabeth lẹni ọdun 27.
Ṣaaju iku rẹ ni awọn mọlẹbi rẹ ti kọkọ korajọ si aafin rẹ ni Scotland lẹyin ti wọn ti kọkọ n kọminu lori eto ilera rẹ.
Wo fidio yii fun ẹkunrẹrẹ.