Adeleke fìdí Oyebamiji àti Salaam janlẹ̀, ó borí ìbò fún sáà kejì

Aworan Ademola Adeleke

Oríṣun àwòrán, IG/AdelekeA.A

Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 4

Gomina Ademola Adeleke ti ẹgbẹ oṣelu Accord ti wọle fun ṣaa keji gẹgẹ bii gomina ipinlẹ Osun.

Ikede yii waye lẹyin to jawe olubori ninu eto idibo gomina to waye lọjọ Karundinlogun, oṣu Kẹjọ, ọdun 2026 yìí.

Ajo eleto idibo, INEC, kede Adeleke lẹyin to bori ni ijoba ibile mọkandinlogun ninu ijọba ibile ọgbọn to wa ni ipinlẹ naa.

Apapọ ibo ti Adeleke ni lojẹ 511,067, to si fidi awọn alatako rẹ lati ẹgbẹ oṣelu APC, Bola 'Ambo' Oyebamiji ati Najeem Salaam, ti ẹgbẹ oṣelu ADC janlẹ.

Èyí ni àkójopọ̀ èsì ìdìbò gómìnà láti ìpínlẹ̀ Osun

Oṣiṣẹ eleto idibo to n ka ibo pẹlu agunbanirọ to duro

Bi idibo si ipo gomina nipinlẹ Osun ṣe waye lọjọ Abamẹta, ọjọ kẹẹẹdogun oṣu Kẹjọ ọdun 2026 yii ni ajọ eleto Idibo ilẹ wa, INEC, ṣe ti n ko esi ibo naa jọ.

Bẹẹ naa si ni BBC News Yoruba to ti gunlẹ sipinlẹ Osun ṣaaju ọjọ idibo n mu gbogbo ẹ wa bo ṣe n lọ.

Eyi ni awọn esi idibo naa bi wọn ṣe n jade lati ijọba ibilẹ kọọkan l'Osun.

Lati maa mọ bi esi idibo naa ṣe n lọ si, maa ba wa lọ lori ikanni ati oju opo yii.

Ni bakanaa, ti o ba ṣe n tẹ ori atẹ esi ìbo to wa ni isalẹ patapata, ni abajade esi ibo fun ẹgbẹ oṣelu kọọkan, pẹlu ijọba ibilẹ ti wọn ti bori, yoo maa han si ọ.

Esi ibo lati gbogbo ijoba ibile ogbon

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Olorunda

Accord 23514

ADC 666

APC 24671

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ejigbo

Accord 18458

ADC 5053

APC 16195

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ife South

Accord 13507

ADC 290

APC 14678

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Olaoluwa

Accord 10063

ADC 213

APC 10782

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Isokan

Accord 13765

ADC 384

APC 14063

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ayedaade

Accord 16681

ADC 331

APC 15719

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Egbedore

Accord 19278

ADC 362

APC 11194

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Atakunmosa East

Accord 7872

ADC 333

APC 9936

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ayedire

Accord 11073

ADC 148

APC 9910

Esi ibo lati ijoba ibile ogun

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Irewole

Accord 10934

ADC 275

APC 29972

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ila

Accord 16211

ADC 259

APC 12934

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ede North

Accord 35427

ADC 307

APC 10283

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Iwo

Accord 27085

ADC 588

APC 19660

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Atakunmosa West

Accord 7479

ADC 213

APC 10037

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ifelodun

Accord 21107

ADC 509

APC 18396

Esi ibo lati ijoba ibile maarundinlogun

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Odootin

Accord 18003

ADC 377

APC 15435

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Oriade

Accord 21343

ADC 423

APC 14863

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Osogbo

Accord 36480

ADC 1503

APC 30474

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Orolu

Accord 12352

ADC 236

APC 10622

Esi ibo lati ijọba ibilẹ mẹwa

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Obokun

Accord 12023

ADC 205

APC 16120

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Irepodun

Accord 14504

ADC 249

APC 15713

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Boripe

Accord 12448

ADC 379

APC 19963

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ife Central

Accord 21171

ADC 747

APC 15913

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ilesha East

Accord 12280

ADC 504

APC 16208

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ifedayo

Accord 7427

ADC 115

APC 6836

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ilesha West

Accord 16196

ADC 673

APC 12756

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ife North

Accord 13879

ADC 333

APC 9613

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ede South

Accord 26188

ADC 390

APC 6219

Esi ibo lati ijọba ibilẹ Boluwaduro

Accord 7118

APC. 7050

ADC 179

Ajọ INEC ti fẹ bẹrẹ kika esi idibo

Ajọ INEC ti fẹ bẹrẹ si ni kede esi idibo

Gbogbo eto ti to ni Osogbo nibi ti ajọ INEC tí fẹ bẹrẹ si ni maa ka esi idibo ipinlẹ Osun tó waye loni.