Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Wahala wa o!
Awọn ajinigbe ji ọpọ eeyan gbe ni Zamfara, wọn tun dana sun ire oko.
Ilu Farin Ruwa tiṣẹlẹ naa ti waye wa ninu ibanujẹ nla bayii.
Ire oko bii ẹwa, agbado ati bẹẹ bẹẹ lọ ṣegbe
Ṣe o ti gbọ pe kurukuru, afẹfẹ idọti ati òòrun yoo bẹrẹ lati Ọjọru kaakiri Naijiria.
Ajọ Nimet to n ri si oju ọjọ lo kede bẹẹ.
Nimet sọ ọna abayọ fawọn to ba ni ikọ Asthma
Ati ohun tawọn ileeṣe ọlọkọ ofurufu gbọdọ ṣe.
Kan si BBC.COM/ YORUBA
Ko ṣẹlẹ ri ma ti ṣẹlẹ ni Kenya!
Ki ni wọn ṣe tẹnikan o ṣe ri?
Aarẹ William Ruto lo ni ki wọn fi ẹgbẹrun lọna ogoji dọla kọle fun Alufaa, kawọn akọrin fi iyoku ṣe ara rindin.
Ni ṣọọṣi ba da a pada, wọn lawọn o fẹ.
Ki lo mu ijọ Aguda kọ owo nla bẹẹ?
