Ìjọba yóò dá iléeṣẹ́ ọlọ́pàá kùsà sílẹ̀ láìpẹ́ nítorí àwn tó ń jí àlùmọ́ní Nàìjíríà wà – Dele Alake, mínísítà ohun àlùmọ́nì

Ìjọba yóò dá iléeṣẹ́ ọlọ́pàá kùsà sílẹ̀ láìpẹ́ nítorí àwn tó ń jí àlùmọ́ní Nàìjíríà wà – Dele Alake, mínísítà ohun àlùmọ́nì

Minisita fun idagbasoke ohun Alumọni lorilẹede Naijiria ni ijọba Bọla Tinubu fẹ gbajumọ bayi fun owo apapsapo orilẹede Naijiria le burẹkẹ sii.

Ninu ifọrọwerọ kan pẹlu BBC News Yoruba, Minisita fun idagbasoke ohun alumọni lorilẹede Naijiria, Dele Alake ṣalaye pe ṣaaju asiko yii epo ti Naijiria n ran oju mọ ko jẹ ko mọ pe awọn guruji to pọ lo sodo si abẹ ilẹ lorilẹede Naijiria.

'A fẹ da ọlọpaa kusa silẹ laipẹ'

O ni ileeṣẹ idagbasoke ohun alumọni ilẹ nijọba apapọ ti n ba awọn ologun sọrọ lọna ati dena ọwọja ọwọja awọn ajikusa wa to n mu ki ijọba padanu ẹgbẹlẹgbẹ owo to yẹ ko wọle sinu aṣuwọn rẹ lati ẹka iwakusa ohun alumọni ilẹ.

Lara igbesẹ to ni ijọba n gbe bayii ni lati da ẹka awọn agbofinro ti yoo maa mojuto awọn ohun alumọni wọnyi silẹ.