Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Oni ni ayayjọ ọdun kẹrinlelọgọta ti Naijiria gbominiria lọwọ ijọba Ilẹ Gẹẹsi
Iyẹn naa daa, a ku ọdun
Awọn araalu sọrọ ilẹ kun lori ajọdun naa (sound)
Kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
Aarẹ Bola Tinubu ti sọ pe ipade nla kan yoo waye fun gbogbo awọn ọdọ orilẹede yii laipẹ
Nibi ti wọn yoo ti jiroro lori awọn ohun ti wọn n fẹ lọdọ ijọba ati ọjọ ọla wọn
Aarẹ lo sọ ọrọ naa lasiko to n ba awọn Naijiria sọrọ loni ayajọ ominira
O ni ọgbọn ọjọ gbako ni ipade naa yoo fi waye, ijọba yoo si ṣe ohun ti wọn ba fẹnuko si nibẹ
Iwọde ebi n pa wa ti waye laarọ oni niluu Eko, Osogbo ati Abuja
Bo tilẹ jẹ pe wọrọwọrọ ni iwọde naa lọ niluu Eko ati ilu Osogbo
Awọn agbofinro fi gaasi tajutaju tu awọn oluwọde naa ka l’Abuja