Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Ṣe a maa sọ pe ina eto ẹkọ Naijiria n jo ajorẹyin ni?

Ṣe ti esi idanwo UTME ti JAMB ni ọpọ lo fidii rẹmi?

Bẹẹ ni, awọn to le ni ida aadọta to jokoo ṣe idanwo ni ko gba maaki igba

Ki la wa le sọ pe o fa a?

Kan soju opo bbc.com/yoruba lati ka ẹkunrẹrẹ iroyin nipa esi idanwo naa

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Ijọba UK ni awọn n ṣe agbeyẹwo eto visa gbigba sorilẹ ede naa

Latari bawọn eeyan lati ilẹ okeere bii Naijiria, Pakistan ati Sri Lanka kii ṣe fẹ kuro ti wọn ba ti wọ ibẹ

Wọn ni ọpọ awọn to fi fisa ikẹkọọ wọ UK lati ilẹ okeere

Lo maa n beere fun eto idabobo lẹyin ti wọn ba wọle tan

Ati pe awọn yoo fofin de bawọn eeyan ṣe n wọ UK lati oṣu karun-un yii

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Iyawo kan, ọkọ kan ni mo maa n gbọ pe Bibeli wi

Bẹẹ ni ko yatọ

Ijọ Pentecostal kan ree ni South Africa nibi ti ọkunrin kan ti le laya pupọ, koda wọn maa n ṣeyawo ọlọpọ ero

Ṣe lootọ?

To ba fẹ ja irọ mi

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́