Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Oniruuru ẹsun la ti gba tako Martins Vincent Otse ti ọpọ mọ si Verydarkman

Ajọ to n gbogunti iwa ajẹbanu ni Naijiria, EFCC lo ṣe afọmọ ọrọ

Agbẹnusọ EFCC, Dele Oyewale ṣalaye fun BBC pe ọpọ eeyan lo kọwe ẹsun sawọn

Pe VDM n tọpinpin awọn lori ayelujara

EFCC ni awọn maa gbe lọ sile ẹjọ laipẹ

Igba wo ni wọn maa tu silẹ?

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Awọn akẹkọọjade kan ree ti wọn kọminu lori bi ajọ NELFUND

Ṣe n fun wọn lẹyawo lati fi sanwo ile ẹkọ lẹyin ọpọ oṣu ti wọn ti kẹkọọjade

Wọn ni ṣaaju lawọn ti beere fun ẹyawo naa lasiko tawọn nilo rẹ

Amọ tawọn ko ri owo naa gba titi tawọn fi wa sọna miiran

To si jẹ n iyalẹnu fawọn pe NELFUND san owo naa fun ile ẹkọ awọn lẹyin tawọn ti pari

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Awọn iyawo ile meji ri ẹwọn kọọkan he fẹsun pe wọn ta owo naira

Atẹjade kan ti EFCC fi sita lọjọ Aiku ṣalaye pe

Ibi eto ayẹyẹ kan niluu Eko lọwọ ti tẹ awọn obinrin naa

Fun ẹkunrẹrẹ awọn iroyin yii

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́