Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Ijọba Naijiria, ẹ yọ orúkọ mi kúrò lára àwọn afurasí tí ẹ n wa

Sunday Adeyemo, Igboho lo sọ bẹẹ.

Igboho ni ibanujẹ lo jẹ foun boun ko ṣe lominira lati le rin kiri ni Naijiria

Iyoku iroyin ọhun wa loju opo wa

;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;

"Aadọta ọdun loni, ìlànà oyè jíjẹ Ibadan ṣì máa dúró digbí.

Itumọ?

Gomina Seyi Makinde lo sọrọ yii nigba to ṣabẹwo si idile Olubadan to waja,Ọba Owolabi Olakuleyin

Makinde ni gbogbo Ibadan ti wa niṣokan bayii.

Nigba wo ni Olubadan tuntun yoo jẹ bayii

Kan soju opo BBC.Com/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ iroyin

'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Mo le ku nitori apo fulawa kan, kawọn ọmọ mi ṣaa ti ri ounjẹ jẹ

Haa ki lo le to bẹẹ, ko ma siku loju rẹ?

Emi kọ o, baba kan tawọn ọmọ rẹ ko jẹun fọjọ mẹrin ni Gaza lo sọ bẹẹ fun BBC

Ajọ UN ti fidi ẹ mulẹ, pe o ti le lẹgbẹrun kan awọn Palestine to ti ku bayii latari ebi

Ki wa nidi abajọ gan an?

Ti o ba fẹ mọ...ẹ kan si wa...